News:

Welcome to platform and forum for Towns, local communities, Small Businesses, business listing, Customers, people, and events etc.

Main Menu
Goat1-airdrop.jpg

The best topic

*

Replies: 5
Total votes: : 1

Last post:
Re: Advertise on NaijaCities App by Adawebs

avatar_Bravebold

Yoruba Proverbs

Started by Bravebold,

Previous topic - Next topic
Hamster-combat-airdrop.jpg
The first post content
Yoruba-proverbs.jpg


Ẹnu ẹyẹ ni ńpẹyẹ; ẹnu òrofó ní ńpa òrofó; òrofó bí ọmọ mẹ́fà, ó ní ilé òun kún ṣọ́ṣọ́.
The mouth of the wild pigeon is its undoing; it hatches six chicks & brags that it's nest is completely filled.
[Not very smart to brag; bragging & boasting can be self-defeating]

 Popular topic   Link

Bravebold

Báa gún iyán, táa ro ọkà fún kòfẹ́kògbà, kò ní fẹ́, kò ní gbà, náà ni
Even if one pounds yam and prepares yam flour meal for a difficult fellow, he'll yet remain difficult.
(Regardless of what you do or say, a difficult fellow can't but be irrational; do your best & move on)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Gbogbo ẹni tó di ojú kọ́ ló ńsùn; gbogbo ojú tí a là sílẹ̀ kọ́ ló ńríran.

Not all those who closed their eyes are sleeping; not all eyes that are wide open are seeing.
(Appearance can be deceptive; look beyond the obvious, always.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Ọmọ ọ̀lẹ làyè ò lè gbà, ibi gbogbo ló gba alágbára. /
Only a lazy person has issues coping, every situation suits a diligent fellow, just fine.
(Diligence pays; often a diligent, 'can do' attitude does make a way, where it seems none exists.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Olójú kan kì í mọ'yì Ọlọ́run à fi tí nǹkan bá gbọ̀n si. /
A person with a bad eye is seldom thankful to God, until a speck enters the good one.
[Attitude of gratitude is it; we must remain ever grateful.]
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Bí kùkùté ṣé kéré tó, kò sí ẹni tó lè fi ẹsẹ̀ fà á tu.

As small as the tree stump is, no one can uproot it with the foot.

(Judge nothing by its appearance; underestimate nothing; what we deem inconsequential may well pack a hefty punch.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

A kì í fura sí ẹni tí a ńbá rìn; ẹni tí a bá ńfura sí, a kì í bá irú wọn rìn.

Do not be suspicious of those you associate with; those you'd be suspicious of, should not be your close associates.

(Build trust; avoid paranoia; be positive and forward-looking.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Bó lé lógún ọdún táa ti fi adẹ́mun jọba, kò ní yé ọrùn ọ̀pẹ ẹ́ wò.

Even after 20 years of being crowned a king, the palmwine tapper won't cease gazing at the palm tree with nostalgia.

(Old habits die hard.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Ọ̀rẹ́ ọdún mẹ́ta ò tó ẹni tí à ńgbára á lé; ọ̀tá oṣù mẹ́fà ò tó ẹni tí à ńsà lóògùn.

A friend of three year is not one to be fully trusted; an enemy of six months is not one to be attacked with charms.

(Be perceptive and be measured; avoid jumping to.hasty conclusions.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Bí imú asín bá gùn, ẹnu ẹlẹ́dẹ̀ kọ́ ló yẹ ká ti gbọ́.

Even if the moonrat has a long nose, it is not the place of the pig to point it out.

(Don't meddle: mind your own business; don't criticise others with far less issues than you are grappling with.)
  •  

Bravebold

Ìbàjẹ́ ènìyàn, kò lè dá iṣẹ́ Olúwa dúró.

The nefarious acts of man cannot scuttle the plan and purpose of God.

(Keep hope alive; man cannot be more than man, yet God remains God; keep moving forward, undeterred.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Ojú tó rí ibi tí kò fọ́, ire ló ńdúró de.

The eyes that saw evil and did not go blind are waiting to see good.

(The best is yet to come; keep hope alive.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Ìwà rere lẹ̀ṣọ́ ènìyàn.

Good character is what adorns a man.   

(Good character beautifies; it is adorable and attractive; bad character is repulsive.)
  •  

Bravebold

  •  

Bravebold

Ìgbà tí ijó bá yẹ'ni là ńkúrò lójú agbo.

When the ovation is loudest is the time one quits the dance floor.

(There is a right time for everything: know the signs of the times; know when to quit: never overstay your welcome.)
  •  

Bravebold

Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò mọ ẹni tó fẹ́'ni.

You do know who you love for sure, but you cannot be certain of who really loves you.

(Be perceptive; things are often not as they appear.)
  •  

Bravebold

Tí a bá ní ká tì í kó dúró; tí a bá tì í tó bá ṣubú, ńkọ́?

If we intend to push it to stand; what if we push it and it falls?

(Think well before you act; don't be presumptuous; things often have the propensity not to go as planned: why moderation is crucial in everything.)
  •  

Bravebold

  •  

🡱 🡳